Kini o wa ninu?
-
9 modulu
-
8 Awọn fidio
-
Iwe-ẹri
Ẹka
Olukọni
gbọdọ wo
DIE SI NIPA ẸKO YI
Gẹgẹbi awọn oniwun iṣowo, ọkan ninu awọn ibẹru nla wa ni sisọnu ohun gbogbo ti a ti ṣiṣẹ fun. Ododọ oro ni pe, o le ṣẹlẹ nigbakugba - ibesile ti ina, ole jija, ikun omi, ijamba ati bẹbẹ lọ.Iṣeduro wa nibẹ lati rii daju wipe nigbati awọn iṣẹlẹ ailoriire wọnyi ba ṣẹlẹ, o koni padanu gbogbo ohun to ni, ati pe ni igba diẹ, gbo nkan a le pada si bi ose wa tele.1. Ki lo mọ nipa iṣeduro?2. Ki l'awọn ero re lori iṣeduro?3. Kini awọn iriri ti o ti ni pẹlu ati lati iṣeduro?4. Bawo ni iṣeduro ṣe n ṣiṣẹ ni otitọ??Ti o ko ba mọ, iwọ ko mọ na niyen. A wa nibi lati rii daju pe o mọ ni pa iṣeduro ati awon anfani re. Eyi je ẹkọ ti o fanimora ati ti o rorun lori Iṣeduro ati Takaful. Kọ ẹkọ ati ṣiṣe iṣowo rẹ pẹlu ifọkanbalẹ.
Koko pataki lati inu ẹkọ yii
-
Bii o ṣe le lọ nipa gbigba iṣeduro ati bii iṣowo rẹ ṣe le ni anfani lati ọdọ wọn.
-
Bii iṣeduro ṣe n ṣiṣẹ ati ohun ti o nireti fun ọ ati iṣowo rẹ .
-
Imọ lẹhin awọn ewu ati imurasilẹ.
-
Awọn iṣiro ipilẹ nipa iṣeduro ti o le jẹ ki o bẹrẹ.